Akọwe ẹgbẹ oṣelu PDP ni Ipinlẹ Ogun, Ọmọwe Sunday Solarin tí o fi aidunnu rẹ han nigba to n ba BBC News Yoruba sọrọ ṣalaye pe bí ẹni fowo ṣofo laasan ni eto idibo tí ...